Smiley face

Iboosi ara adugbo! Awon omo Unilag ti won lọ sode ariya ti poora



Arabirin kan lori ẹrọ twitter lo kede wi pe, awon omo ileewe Unilag bi ogun (20) kan lo sode ariya lọjọ Aiku to koja yii,  ati wi pe, meta pere lo pada wale ninu won. Awon meta to si pada naa, ẹkun ni won sun bi egbere.

Isẹlẹ naa fe jọ iru eyi to sẹlẹ ninu sinima Jenifa.

Titi di akoko yii, a ko ti gbo ohunkohun lati ọdọ awon alase ileewe naa lati fidi oro naa mule



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment