Smiley face

Kini ka se si awon olukọ ileewe giga ti won lo ipo won fun iwa ibaje?



Aimoye awon akekọọ nile ẹkọ giga lo wa ninu ibanuje latari awon oluko ti  won leri lati ba aye won je ninu ẹkọ ti won ba ko lati je ki won ba won lajọsepọ.

Aimoye akekoobirin lo si ti gba iru ẹgbin, idoti ati iwosi yii mọra latari wi pe won ko lagbara. Bakan naa lori pelu awon ileese nla wa kaakiri orileede wa.

Kini ọna abayọ si eleyii?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment