Smiley face

Oba alawada meji: Sanyeri gbena woju Mr. Ibu


Ogbontarigi alawada onifiimu Yoruba, Sanyeri ati MR. Ibu to je okan gboogi laaarin awon alawada fiimu onigeesi ti Nollywood Naijiria ti setan lati gbe sinima tuntun kan jade bayii.




Ohun ti a gbo ni wi pe, fiimu naa ko ni pe jade.

E ku oju lona!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment