Smiley face

Omo Ayo Fayose n se faaji ninu ola

Okan ninu awon omo gomina Ayo Fayose ni yii ti oruko re n je Rogba. Rogba lo se afihan foto yii lonii lori ero ayelujara ninu olanla baba re. Sebi Yoruba lo ni, ola abata ni i modo san...
ola baba omo ni i momo o yan
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment