Smiley face

Omo Gomina Ajimobi wọsọ N1.4M lọ sariya

Okan ninu awon omobirin Gomina Ajimobi lo wose yii. Nigba ti awon eniyan yoo lọ wo iye owo aso naa  lori igba, won ri wi pe, iye owo aso naa n lo bi nnkan bi N1.4M.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment