Smiley face

"Ori ayelujara ni mo ti kọkọ gbọ pe iyawo mi ku" - Jide Kosoko

Nibayii ti Omooba Jide Kosoko si n sọfọ iyawo rẹ to doloogbe lọjọ Aje to koja yii. Oserekunrin naa ti salaye bi won se tufọ iyawo re naa fun un. 
 
Gege bi alaye re, o ni ipade kan ti oun wa ni won ti wa gbe iroyin naa si oun leti wi pe, iroyin kan ti n fo kiri ori ẹrọ ayelujara nipa iyawo rẹ.
"Lowo kan naa ni mo pe ile lati mo boya otito ni ọrọ naa. Si iyalenu mi, wo n jẹri si wi pe otito ni. Ọkan mi baje, iyawo ẹlẹẹkẹta ni yii ti yoo ma ku mọ mi lori nigbesi aye mi. Ki lẹ lero wi pe awon aye yoo ma sọ nipa mi bayii?" Jide Kosoko fi ibanuje re han

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment