Smiley face

Toyin Aimakhu n gbadun aye re leyin gbogbo laasigbo to waye

Gbogbo igba ni Toyin Aimakhu n dunnu pẹlu awon aworan orisiirisii ti omoge onitiata naa  n fi sita. 


Ọ jọ bi ẹni wi pe o ti gbagbe gbogbo ateyin wa rẹ pata. Bakan naa, se o gbagbe, omobirin naa ti ni oun ko ni fẹ eniyan dudu mọ; o ni oyinbo alawo funfun lo ku ti oun tun le yan gẹgẹ bi ọkọ.
Anti Toyin, ko si ohun to soro se, Olorun yoo gba fun ọ.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment