Smiley face

Aye Akamara: Kini won fe fi omo ti won so mole se ni Sango ota?


 Omokunrin ti oruko re n je, Taiwo Korede, ni won ri nunu igbekun ijo Celestial Church of Christ (Key of Joy Parish, Ajiwo) to wa ni  Ajibawo ni ijoba ibile  Ado Odo/Ota, ipinle Ogun.


Atejade ti ajo NSCDC ti won ri omo naa fi sita ni yii:
“On the 22nd of July 2016,at about 10:30hrs at Ajibawo in Ado Odo OTA Division 2, NSCDC officers rescue a boy, named Taiwo Korede, aged nine years old, who had been chained for weeks at Celestial Church of Christ key of Joy Parish Ajiwo.


“The case has since been transfer to the appropriate authority for further investigation.”


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment