Smiley face

E wa wo bi won se sun adigunjale bi suya l'Owerri

O ti to bi ojo meloo kan seyin bayii ti awon adigunjale ti n da alaafia awon eniyan ilu Owerri to wa nipinle Imo laamu.

Sugbon gege bi Yoruba ti wi, ojo gbogbo ni tole, ojo kan pere ni ti "the owner".


Eleyii lo sele nigba ti okan ninu awon ole ti won wa se ijamba lonii ko sowo. Ikanra ni gbogbo ara ilu fi dide, ti won si dana sun maanu naa laaye.

Sugbon sa, awon kan ni ko ba dara ti won ba le fa ole naa le awon olopaa lowo lati fiya to ba to je e labe ofin ju idajo owo ara won lo.

Kini ero yin lori eleyii?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment