Smiley face

[Foto] Saheed Osupa ati Baba Wande ninu ere T'Oluwa Nile

T'Oluwa Nile bi ti bawo? Heheheheheheh! Rara o, ko ri bee.

Bi o tile je wi pe Saheed Osupa ti n korin ti pe, sugbon o daju wi pe opo eniyan ko ti mo Osupa nigba naa.

Nje eyin tile ranti odun ti T'Oluwa Nile jade?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment