Smiley face

Ifẹ si n gbona bi ajere lẹyin ọdun karun-un ti won ti se igbeyawo

Awon Yoruba bọ, won ife ni akoja ofin. Ife si bori ohun gbogbo. Ifẹ kan naa yii lo ti mu toko-taya yii, arabirin Tynedria Meneweather ati oko re, Pendariu, maa gbe lati bi odun marun-un seyin.
 
Ose to koja (03/07/2016) yii ni awon mejeeji se ajọyọ ọdun karun-un ti won ti so yigi won.
 
Adura mi ni wi pe ki Olorun se iru ire ayọ nla bayii fun gbogbo awon okunrin ti won waya. Ki awon naa kuro lẹgbẹ apọn, ki won si di alaya nile.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment