Smiley face

Iyanu! Toko-taya pada tun yigi won so leyin odun mokanlelogbon (31) ti won tuka

Omo won lo kede eleyii lori twitter. Leyin odun mokanlelogbon (31) ti won ti daru fun ara won, won tun pada so yigi naa pada pelu akara oyinbo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment