Smiley face

Ohun to sele leyin ti iya omo yii ku ninu ijamba oko

Nnkan mbe ni duniyan. 

Mama omode yii la gbo wi pe o ku sinu ijamba oko. Leyin isele yii, ti won ba gbiyanju lati fun omo yii lounje ko ni gba ounje naa lowo enikeni.

Baba omo yii wa da bi ogbon, o gbe foto iya omo naa soju, omo naa si bere si ni gba ounje naa je pada lati akoko naa.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment