Smiley face

Ore ibeji lodun ibeji awon ibeji Olajire

Awon olorin ẹmi bi aadọta (50) ni won ti setan lati kọrin, pẹlu ọkẹ aimoye awon eniyan lagbo amuludun ni won ti n mura lati pejọ yọ pẹlu Ibeji Olajire lọjọ kokanla osu kesan-an odun yii, 11/09/2016, nibi ti won ti ma se ifilọlẹ awo orin won tuntun pẹlu ayẹyẹ ọjọ ibi won ninu gbongan nla to wa nile orin Yinka Ayefele niluu Ibadan.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment