Smiley face

Won fi ilu ki King Sunny Ade kaabo siluu Amerika

King Sunny Ade

Leyin ti King Sunny Ade si ileese Redio re to wa niluu Ondo, Agbaoje olorin juju naa ti koja lo siluu Amerika bayii nibi ti awon otookulu onifaaji ti n reti re lati wa fi orin da won lara ya.


 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment