Smiley face

Won ti mu omo Aare Buhari wo agbo awon amofin lonii.

Halima Buhari, okan ninu awon omo Aare Muhammadu Buhari, lo ti yege bayii lati darapo mo awon amofin ile Naijiria leyin to yege ninu awon idanwo re gbogbo.

Ayeye igbawole sawujo awon amofin yii lo waye lonii nibi ti awon ebi Buhari ti gbe parapo lati wa ye Halima si.


Lara awon to wa nibi ayeye naa ni mama won to je iyawo Aare Buhari, Aisha Buhari. Lara awon omo won to wa nibe ni Zahra, Yusuf ati awon yoku.

Nnkan bi ojo meji seyin naa ni Zahra ati Yusuf kawe gboye jade nile eko giga kan niluu oba Elisabeeti.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment