Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (1)

#AyeOlabisiK @OlayemiOniroyin

 Itan igbesi aye Olabisi K (1)
Awọn Yoruba ni oju ẹni maa la, dandan ni ki oju naa riyọnu. Itan yii ti fi igba kan kọkọ wa lori Yoruba Dun ni odun 2011; ibẹ lati kọkọ gbe itan naa jade. Sugbon bayii, a ti gbiyanju lati se akojọpọ itan naa ki won le wa loju kan naa lori Olayemi Oniroyin. Sebi omi ẹko, ẹko naa ni.

Ka rosọ mọdi, ka rodi masọ sebi kidi ma ti wa lofifo naa ni gbogbo ọgbọn tan an da.

Arabirin Olabisi K ni isele naa sele si, Olabisi K si ni awon eniyan mo si i lori Yoruba Dun nigba ti leta naa kọkọ jade.

E je k’emi dake nibi na, nigba ti Olabisi K yoo maa fi ẹnu ara rẹ salaye awon iriri rẹ pata sinu leta rẹ. Sugbon ki n to dake, sekaseka ranti atunbotan. Bo o ba laye o seka, bo o ba ranti iku Gaa ko sotito. Nitori ti ogun ba jẹ lọ, ọgbọn a maa jẹbọ.


Sii Olootu Yoruba Dun,

Inu ibanuj ni mo ti n k lta mi yii si yin. Mo padanu baba to bi mi ni kete ti mo pari ile iwe girama. Sugbon mo pinnu lati tesiwaju k mi lab botiwukori lyin iku baba mi. 

Mi ò ni f gba yin lakoko pupọ nipa alaye ogun ti awon idile baba mi gbe ko iya mi, wahala ile olorogun ni ori y o dile. m meji pere ni iya mi bi, obirin kan ati okunrin kan. Emi si ni obirin ti mo si tun j gbn.

Pelu agbara Olorun ati atilyin iya mi ti n fi ounj tita sr aje, mo pari iwe giga mi ni nnkan bi odun mta syin.

lburuk si ni Oluwa, kete ti mo pari ile iwe ni ba oke pese ise fun mi ni ile ise agbase se kan ni ilu Eko.

Sungbn ìsòro ti mo ni ni wi pe, ga tuntun ti won ss gbe wa si ile is wa ni dandan ni oun f ba mi sun ni tipa. O ti to osu kan bayii ti o ti n y mi lnu.

Awada ni mo kk pe r naa sugbn o ti n dooto bayii. Bẹẹ ga yii lagbara ati dami duro lnu is ti nikni ko si ni yẹẹ lw wo.

Bẹẹ ni mi ò setan lati fi is mi sil nitori ib ni mo ti n ran iya mi ati aburo mi lw.

k afesna mi naa o ti rise kan se dabi-alara; oun naa si n was ni. k afesona mi gba mi nimran ki tun b maa b ga mi wi pe ko fi mi lrun sil

Sugbn ga naa ko setan lati gb b mi. Lowlw bi mo se n k lta yii, gbogbo igba lga yii maa kanra m mi, to si ma fise pami lori. Joojum lo si maa dru ba mi wi pe, oun yoo dami duro lj kan ti mi o ba dkun agidi mi.

dakun, gbami nimran.
Emi ni ti yin ni toot.
Omidan labisi K.
 
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment