Smiley face

Adekunle Gold: Ijinle orin lagbara lati gba emi la lowo iparun

Adekunle Gold
Agbara orin ko lounka, eleyii to le sisẹ fun iwosan, bakan naa ni orin le gba emi eniyan la lowo iparun. O wa lọwọ bi olorin se lo agbara orin rẹ lati ni ipa ninu igbe aye ẹda.
Aimoye orin ni Adekunle Gold ti gbe jade saaju to niise pelu ọrọ ifẹ. Sugbon omokunrin olorin to wa lati idile oba yii ti jẹwo ara gege bi ojulowo olorin pelu bo se gbe orin re gba ona ara tuntun, eleyii to kun fun ijinle ọrọ ati isiti.

Ka ma parọ, aimoye ọrọ ọlọgbọn lowa ninu ARIWOKO eleyii ti n se ọkan ninu awon orin to wa ninu awo rẹ to pe ni GOLD.
Ohun to daju ni wi pe, aimoye odun sigba taawa yii, orin yii yoo ma sise itura, ikilo, isiti eleyii to lagbara lati se igbala emi fun awon ti igberaga, ayo-ayoju, ati bamu-bamu-layo ko ba ti sekupa.

 
Lati ni odindi awo tuntun Adekunle Gold lowo, eleyii to pe akole re ni GOLD, E wole SIBI.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment