Smiley face

E wa woju ojulowo omo Yoruba: Olori Ademidun Adetoro Fagbenro gbayi!


Oni ni ojo ibi Olori Ademidun Adetoro Fagbenro, ojulowo omo Yoruba to yaayi to tun logbon lori ni, orekelewa obirin ti ki i rinrin idoti lojokojo. 

Gbogbo wa pata laba oloriire eniyan yo loni. Ire owo, Ire omo,, igbega ati emi gigun. Ase


Bayii ni Olori Ademidun Adetoro Fagbenro se gbe ohun ope re soke si Oluwa
"Kabiyesi Olodumare,Oba to to to,Oba Lanaa,Oba lonii,Oba titi ayeraye.Olorun awon Olorun,Oluwa awon Oluwa,Oba awon Oba.Oba to tele bi eni n teni,Oba to ta sanmo bi eni taaso, Oba to lo kanrikese...... "

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment