Smiley face

[Foto] Nothing Hill Carnival odun 2016 lekenka niluu London

Awon Yoruba lonii odoodu laa rorogbo, odoodun la rawusa. Sebi todun ba ti dun laa romo obi lori ate. Nothing Hill Carnival 2016 tun ti wole de, odun ariya, faaji ati ajoyo nla eleyii to maa n waye lodoodun niluu London.

Aimoye awon eniyan kaakiri agbaye ni won ma n gbe ori wo ilu London ni asiko ariya Nothing Hill Carnival yii. 
Niwon igba to je wi pe aimoye omo Naijiria ni won gbe niluu London, awon gan-an ki i si gbeyin ninu ariya naa pelu bi won se ma n pagbo ti won segbe kan ti won pe ni Naija Corner. 
 Odun 1966 ni ariya Nothing Hill Carnival bere ni san-ansan. Bakan naa ni mo si tun ki yin kaabo si todun yii, eleyii to tun palemo.









Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment