Smiley face

Happy Birthday Oluwafemi Oladele - Femi Solar ( King of Jasa Music

E fi efun pale laro. E pagbo orin idunnu, E mu ikoko obe to jin koto ke e fi gbesu kana. Bisu bajina tan, e kosu sinu odo ke e gunye ire ti won je l'Ekiti ti n joni lowo joni lenu. 

Ti won ba ni tori taani, e wi fun won pe tori Oluwafemi Oladele ni, Baba Rokan sebi ere-bi-ere di baba nla. Ogbontarigi apade ara di Oorun ti ko se siju wo loke.

Olayemi, mi o ni soro ju lonii, won ti fe so mi lenu pe oro mi po. Sugbo mo gbadura ire owo, ire omo, ayo, okiki, emi gigun ati alaafia fun olojo ibi. 

To ba lo igba odun laye, walahi, 1day ni won yoo fi ka funo lode orun. Amin. 
#HBDFOS #HBDKingSolar HBDKingofJasa

E ma gbagbe wi pe, anfaani ti wa bayii lati ni awo orin tuntun Femi Solar to pe ni Mercy Beyond lowo. E na wo mu ti yin NIBI.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment