Smiley face

Tewe-Tegbo Yoruba: Itoju eti to n yo oyun


Ti eti ba dun enikan, ti eti naa ba n yo oyun, bayii ni a se le se iwosan re ni ilana ibile Yoruba.

A ma wa Kokoro ika modu tanpeni ikandu bi ogun. Leyin eyi ni a ma re awon kokoro naa sinu oti ogogoro fun ojo meta. Eleyii yii yoo mu toro daada sinu oti yii. 

Ti awon kokoro yen ba ti toro daada tan sinu oti, a ma fi owu fi ma kan omi ogogoro naa sinu eti wa, laaro ati ni ale

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment