Smiley face

Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (27)

AyeOlabisik27
 
Ẹ le ka itan igbesi aye Olabisi K to ti jade tẹlẹ NIBI ki ẹ to tesiwaju lati ka eleyii ki itan naa le yeyin daada
Yoruba Dun: Itan igbesi aye Olabisi K (27)


Eyi ni awon esi ati amoran ti awon eniyan fun Olabisi K lori leta re to ko gbeyin. A ko se atunse tabi atunko si awon oro won, bi won se kọ gẹlẹ naa la tun tẹ



Aríyíbí Qósìm Adésolá: Ó ga ò.
Taiwo Bukola Eunice: Gbaluke Hun,o so sini lenu bee lo buyo sii pelu.


Ogundijo Nureni Siyanbola: Olorun yio je ki oga oloriburuku yii ko ko ti e niwaju,mo si fe ki e fija fun Olorun ja.Sugbon iba dara ki e mo je ki oko yin o mosi tori to ba mo si ko si ojo tio le ronu debe ti inu re ko ni baje



Abdullahi Bola: Orisirisi okunrin rere lo wa, sugbon okunrin bii oga re yi oloriburuku okunrin ni. Odun mi pe opada ba o lasepo tori be lofi fise sile. O se asise ni ki owo agbofinro file tee ni. Idajo nbe lorun oooo.



Obadimeji Ayinde: Don'noru Abdulhafeez @su nuraini,ki okore mo nisin odaju ki opadamo lojo iwaju,bcus ore okore timo,kosi ogbo ki okore mamo,and ti obasepe ife odo ni iyan kodina ifewon,rara.

Rosheedat Bamidele Amusat: E pele o. Eledumare a gbe ija yin ja.

Adegboyega Siji: Nibi ti oro de yii,mo ni idaniloju pe Olorun yoo fi oju eni ibi yii han,asiri re yoo tu.O di dandan ko gba idajo Olorun.

Ashabi Omolawlah Adejoke: Eledumare,afi omi ati eje eni tondayin lamu,afi da lamu

Adebisi James Adebayo: Oga ooo...

Omotola Ajayi: Oga buruku waje re ise öwö e.laye wa tun je lorun

Sunday Giwa: E pele o olorun a ko e yo o koni si arun lara ogbeni were na o.

Royalty Adetola Ademola: kii bani ka ma se 'ha', bee a kii se 'ha' ko ma gb'omi loju eni. Ohun ti mo fe ki Olabisi mo nipe ohun ti eda o ba fi se itan pa aye yii naa ni yo kuku baa atipe o wu Olohun ki ohun to sele yi o sele ni bi beeko, se a ko dabo re to ni? E woo, e pa okan po si odo Eleduwa, o damiloju pe Olohun ni ipinnu rere fun yin ategun si ibudo aseyori ni idanwo yi maa je.

Orobiyi Olaide: E pele o, olorun a gbe ko oni ti e

Oladayomi Mary: Olorun a dide igbenija nitori yin. Amin.

Oyejide Simeon: Awidobori to ta soke,omo pe olorun asesan,

Adegboyega Siji: A n reti leta miiran lati mo ibi ti oro naa yori si.

Bukola Toyin: Ogao, Aanu yin semi gan ni .Oun na mapade eni toju lo.

Adebisi Taiwo Hassan: Iru eleyii labe orun wonderful

Abudu Oluwasegun Coded: Olorun a re yin lekun o amin


Ẹ tẹsiwaju ninu itan igbesi aye Olabisi K NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment