Smiley face

[Foto] Ooni Adeyeye Ogunwusi ni ilu Amerika- Afikun 1

Bi o tile je wi pe o ti se die ti Ooni Ojaja ti pada wale lati ilu Amerika, irin-ajo re to waye ninu osu kefa odun yii. Pupo ninu awon aworan ayeye to waye niluu Amerika ni a ko ti se afian won. Die lara awon foto Ooni Adeyeye Ogunwusi ni yii niluu Amerika. 































Orisun: Tunde Alabi
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment