Smiley face

Ohun ti oju ole n ri ni yii

Okunrin yii lagbo wi pe o n gbiyanju lati jale ninu gbongan ti awon eniyan ti wo boolu. Sugbon okunrin naa ba ibinu awon eniyan pade pelu bi won se ge lowo gege bi ijiya ese re. 
Eni to gbe foto naa sori Facebook ko so ibi ti isele naa ti sele ati oruko okunrin naa.


Foto: Precious Eze




Afikun iroyin leyin atejade akoko: A ti paada ri gbo wi pe, ilu Akwa Ibom ni isele naa ti waye. Telifisan ti awon eniyan si fi n woran ni okunrin naa fe jigbe.


Sugbon, nje o wa dara bi won se se idajo okunrin naa bayii?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment