Smiley face

[Audio] "Mi o le gbagbe ọjọ ti mo kọrin lode ariya lai si irinsẹ" - D-Rọmọla

D-Romola ori eto Gbedemuke pelu Olayemi Oniroyin
Gege bi ọrọ Seun Awodele, "ẹda ti yoo ba tan laye o di dandan ki iru ẹda bee nítán". Eni ti ko nitan ko le tan. Eyi to tunmọ si wi pe , àselà kan ko gbọfẹ laye, olohun ti n nani. 
Ninu ifọrọwerọ mi pẹlu D-Romola, gbajugbaja onkorin ọmọ Naijiria to fi ilu ọba Biritiko se ibujokoo, o so pupo ninu iriri rẹ saaju ko to de ibi to de lonii,

Bakan naa lo tun so fun mi nipa igbiyanju rẹ lati jumọ kọrin pẹlu Tope Alabi ninu awon ise rẹ ti yoo jade lọjọ iwaju.
E le gbọ awọn alaye D-Romola NIBI



E le kan si D-Romola lori; FACEBOOK
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment