Smiley face

Yemi Shodimu gbarada pelu ojulowo aso ibile Yooba

  
Iro ko, oloju agbohunsafefe to le mu ede Yooba ati Geesi papo lori agbegbe lai laagun labiya. Ki i se wi pe ede ni ko ye won, ogbon iroyin igbohunsafefe lo nira.

Sugbon iru kan-un ko pe meji lawujo okuta. Bee iyo ko se fiwe erupe ile laelae. Oga nla ni Yemi Shodimu ninu agbedegbeyo onise opolo to fakiki. Atotun-atosi ni fi n ko yeriyeri bi ina ilagbede.

Asa ile Yoruba ye omo Shodimu, bee ni maanu naa gbo faari pupo. E wo asa Yoruba bo se gbayi lorun Ajani.

Ka ma paro, awon agbada yii LE KU!

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment