![]() |
| Mercy Makinde |
Oni ni ojo-ibi Arabirin Mercy Makinde to je oludasile Iaspire Radio. A gbadura ire owo, omo ayo, alaafia ati emi gigun fun akoni obirin ti n se ise ribiribi lati mu igbe aye awon eniyan tesiwaju.
Igba odun, odun kan ni.
![]() |
| Mercy Makinde |
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
11/12/2016 10:49:00 am
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment