Smiley face

Ohun ti Toyin Aimakhu se nigba ti won pariwo ole mọ Seun Ẹgbẹgbẹ ni yii


Ni awon akoko ti awon eniyan pariwo ole, barawo le Seun Egbegbe lori ni Computer Village to wa ni agbegbe Ikeja niluu Eko latari bi won se lo n gbiyanju lati ji foonu ti iye owo rẹ le ni milionu meji salo; ibudo ere fiimu ni Toyin Aimakhu wa pelu awon akgb r.


Bi o til je wi pe iroyin naa kan Toyin lara, sugbon ko fi ibikankan kobiara si iroyin naa.

Boya ko f ko se idiwo fun is r ni tabi o kan wu u lati ma kobiara si isl naa ni.

Sugbon sa, gbogbo iroyin to n jade ni akoko naa ni won se apejuwe Seun Egbegbe gẹgẹ bi k atijo Toyin Aimakhu. 

Bi awon oniroyin se n daruko Toyin Aimakhu ninu awon iroyin won ko ba ibi to dun lara awon ololufe Toyin eleyii ti awon si n fi aidunnu won han kaakiri ayelujara.
Won ni se ko pọsibu fun awon oniroyin lati kọ iroyin won nipa Seun Ẹgbẹgbẹ lai darukọ Toyin ni?

Seun Egbegbe j ololufe ti Toyin Aimakhun ba l nikete ti ija b silẹ laaarin oun ati k ti won so yigi r fun, Johnson Adeniyi.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment