Smiley face

Ojo ayo lonii je fun Goodluck Jonathan

Aare ana, Goodluck Ebele Jonathan, pe eni odun mokandilogota (59) lonii (20/11/16).

Kaakiri agbaye ni won ti gbe oriyin fun GEJ pelu bo se gba f'Olorun nigba to fidiremi ninu eto idibo odun 2015 to si tun gbe ijoba sile fun Buhari nirowo-rose. 

Sugbon sa, opolopo awon onwoye lagbo oselu ni won gba wi pe, ijoba oko Mama Peace lo si faye gba jegudujera julo ninu itan isejoba ile Naijiria, ilu to n san fun wara ati oyin.

Jugbogborelo, ojo ayo lonii je fun idile Jonathan, idi ni yii ti a fi n ba won yo. Igba odun, odun kan ni! #HappyBirthdayGEJ
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment