Smiley face

Seun Ẹgbẹgbẹ si wa ninu atimọle- awon ọlọpaa lo sọ bẹẹ

Seun Egbegbe
Iroyin arumọjẹ kan ti awon ololufẹ Seun Egbegbe gbe jade lana wi pe, maanu olootu fiimu agbelewo naa ti won lo ji foonun'Ikeji wa nile rẹ nibi o ti n fi ẹja tutu jẹ amala dudu. Won tilẹ sọ wi pe gbogbo iroyin to jade nipa wi pe maanu jale lo je awon ọrọ ti ko lẹsẹ nilẹ.

Sugbọn sa, ninu iroyin tuntun to jade lonii (24-11-16), awon olopaa ti fide rẹ mulẹ wi pe, ololufẹ Toyin Aimakhu nigba kan ri, si wa ninu kolo awon pelu ete ẹnu rẹ ti awon ara ọja Computer Village ti fọ petepete.


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment