Smiley face

Bukola Adeeyo: Ojo-ibi Kara ọmọ alagogo idẹ kun fun ẹkọ gidi

Bukola Adeeyo- (Kara)
Awon Yoruba bọ, won ni bi ọmọ ẹni ba dara ka wi, ki i sebi ka fi saya. Ọpọ awon eniyan ni won sare sidi isẹ tiata to ri "ki won le roju emi naa". Bẹẹ isẹ tiata ki i se isẹ yọbọkẹ fun awon òpè rara.

Bi eniyan ba wo sinima KARA yoo gba wi pe ẹbun Bukola Adeeyo koja keremi. Kara ọmọ alagogo idẹ lọgbọn ori bẹẹ ni ọgbọn atinuda rẹ kọyọyọ.
O ni (18-12-2016) ni ọjọ-ibi orekelẹwa naa. Ẹ gbọ ohun ti Odunlade Adekola so nipa rẹ
"What can you say about this lady Bukola Adeeyo on her special day? To me, she is humble, determined and always stand to achieve. She joined the industry years ago to forge her name on the platform of superstars by being submissive and industrous. I present to you the award winner 'Revelation of the year, Female' BON AWARDS. HAPPY BIRTHDAY TO YOU."
Kemi Afolabi, ogbontarigi oserebirin ilẹ Naijiria naa ko sai sọ nipa iriri rẹ nipa irawo tuntun ti n tan bi orun yii. Ohun ti osere naa wi ni yii:
"Hmmmmnnnn I still remember how reluctant I was to associate with you cos of my past experience with up coming act due to my very open nature which is often taking advantage of...but because you're the closest to my very special goddaughter @kunmipearl122 our path always cross! 

And Sholakunmi will always give me that "cheer up nowww" look😁(wen I been dey frown the whole tym LOL😂) weneva we had to be in same place same time.

Long story cut short ! Time showed me how gentle, respectful, well trained and what a beautiful soul you are in and out!

Don't you worry about whether you're going to become that mega-super-star, trust me! You're going to attain that height you ever want to get too and beyond by Gods grace cos you're one focused chick who sure knows the act.forget stature! You can act🙋👏👏👏👏
God bless your hustle my dearln🙏HAPPY BIRTHDAY" 
Ohun kan kan pataki ni awon irawo nla meji yii mẹnu ba ninu alaye oke yii ni: Iwa Omoluabi

Ti eniyan ba ni ọgbọn ori, to si tun lẹbun, bi ko ba si iwa omoluabi o dabi buredi ti won ko sori igbá ti kò rasọ bora ni. Iru buredi bẹẹ ki i niyi lojo araye.

Ẹ tun wa gbo ohun ti ọkan lara awon ololufẹẹ Kara so lori ayelujara:
"@crownwealth17: Age with grace Bukola Adeeyo just do like you dey do no igberaga in ur attitude hav been reading all ur birthday wishes since more infact am proud of you..... Anytime you are in egba branch for your birthday gift @ panseke market"
Kara, orekelewa omoluabi onise ọpọlọ to fakiki
Kilo wa tun ku ta a fe sọ? Eefin niwa! Awon Yoruba si ni iwa loba awure. Ẹ jẹ ka toju iwa wa daradara. 
 
Adura lasan ni mo fẹ se. Mo gbadura owo, ọmọ, ayọ, ire, alaafia, ẹmi gigun, itesiwaju ati igbega fun omo olojo-ibi. Asẹ!
 
Igba odun, odun kan ni. #HappyBirthday
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment