Smiley face

"Fayose...gomina daadaa ni" - Awon ọmọwẹwẹ ipinle Ekiti

Jesu Olugbala araye ni, " ẹ jẹ ki awon omode wa si ọdọ mi, nitori iru won ni ijoba Olorun". 

Oro yii ni a le so wi pe Gomina Ipinle Ekiti, Ayodele Peteru Fayose n tele pelu bi awon ọmọde se surubo o nigba to se abewo si Okesa lopin ọsẹ to kọja.
Gomina pin ọgẹdẹ ati ẹpa fun awon omode, inu awon ọmọ naa dun. Won si bẹrẹ si ni korin wi pe, "Fayose....gomina daadaa ni. Fayose...gomina daadaa ni. Fayose....gomina daadaa ni"
 


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment