Smiley face

Princess Elizabeth Onanuga: Isẹ kekere kọ ni Boss Lady ati Toke Omo London

Princess Elizabeth Onanuga
Ọjọ Kẹwaa osu kokanla odun yii ni orekelẹwa naa wa sori eto Gbedemuke nibi to ti n se alaye nipa awon akitiyan re re lori sinima re meji otooto ni n bo lona, BOSS LADY ati TOKE OMO LONDON.

Princess Elizabeth Onanuga ti gbogbo eniyan tun mo si Hadiza ko sai menuba idasilẹ ẹgbẹ rẹ tuntun, Divos & Divas Drama Group, eleyii ti won gbe kalẹ niluu UK lati je ri ki isẹ tiata di irorun fun awon to nifẹ si ise sinima.

Divos&Divas Drama Group
Divos&Divas Drama Group
Listen to "Olayemi Oniroyin on Gbedemuke 10-12-16" on Spreaker.

 Oni [14-12-16] ni ọjọ ibi agbaọjẹ onise tiata, Princess Elizabeth Onanuga. Gbogbo wa ni a ba oloriire yoọ lonii. Igba odun, odun kan ni. #HappyBirthday
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment