Barack Obama n serepa lori oni
Faaji ni Barack Obama n se kaakiri lati igba to ti fi ipo re sile fun Donald J. Trump gege bi aare ile Amerika. Lana ode yii, Feb 6, ni won ri oko Michelle lori omi ti n serepa pelu ore re atijo kan.
Reviewed by Olayemi Oniroyin
on
2/07/2017 09:33:00 pm
Rating: 5
0 comments:
Post a Comment