Smiley face

Okiki ati ebun amutorunwa 2nde Glorious lekenka

Aimoye igi ni i be nigbo ki won to firoko joba. Bee si ni kinihun ko leran to tobi ju niju, o wu Edumare lo dade nla fogidan ololaaju.

Ti a ba n so nipa ojulowo onise oge, onkorin ti Edua oke fun lebun gidi, oga ni Adeniyi Tunde Zechariah ti gbogbo eniyan mo si 2nde Glorious.

Bakan naa ni imo re nipa igbohunsafefe ati ise sinima sise ko kere rara.

Omokunrin yii se alaye nipa akitiyan ati awon aseyori re fun olootu RONISHRATI, alaye naa ni yii nisale.
http://ronishratis.blogspot.com/2017/01/interview-am-multi-talented-model-song.html

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment