Smiley face

Aso oge Lara Olubo ta lenu

Bi omo eni ba dara ka wi...awon Yooba lo so bee. Ko si ohun to buru taa ba so nipa ohun to dara to si wuyi loju.

Ka ma para, aso oge Arabirin Omolara aya Olubo ta lenu yeriyeri bi ata suya.

Yato si wi pe arabirin yii je sorosoro ori afefe, okan pataki lo tun je ninu ise oge sise ile Afirika. Ile ise iranso re, Kostobu Stitches, ti gba irawo kari agbaye ninu ka ba ni ranso to jojungbese.

Eyin naa, e wole, ke e wenu oko.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment