Smiley face

Baba olowo yafunyafun ayelujara ti yari ooo. E wa gbo ohun to so

 
Baba olowo yafunyafun ori ayelujara ti oruko re n je Hushpuppi ti kede wi pe oun ko saanu mo. Laipe yii ni Hushpuppi, omo Naija to n gbe niluu Malaysia kede wi pe oun fe ran ogorun eniyan lowo. Sugbon dabi eni wi pe o ti yi ero re pada.

  




Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment