Smiley face

Foto oku Allwell Orji to ko somi niluu Eko (E sora fun aworan abanilokan je)


Okunrin dokita ti won pe oruko re ni Allwell Orji, eleyii to be sinu omi lati ori afara 3rd mainland to wa niluu Eko, ni won ti ri oku re fayo bayiii ninu omi. Awon agbofinro ti kan si ebi okunrin naa lati wa gbe oku re.

Allwell Orji lo be sinu omi ni ojo Aiku, March 19to koja yii. titi di akoko yii, enikeni ko le so idi ti okunrin naa fi gba emi ara re.

https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEizKrmwnL8Lgl-oCTSnxb5KvM5GEOLuF2q-Rpu3E-i33-BBo4NtUEw77lv9gUCLLrYmgmn1fUvzMQuQfleoULSzT4GnmEmby9kxfw1XVKmra2xpBOfPgtTPsJ9-e3JzlgKnrlJiOmbylsYs/s400/z.png 
https://blogger.googleusercontent.com/img/b/R29vZ2xl/AVvXsEjUTHf03nl36b6hYrc0_F2p_zM8MMvZ3BotV2Py3nRLbBHYwuwpTXCXfd3A6mFqVlqxPV8B9w6LvKOqRFni7M8dmmbOoIw5byjbfs21h6LSTMQhtMevf9Ey8PBnEVjvfJhfEibzUyNqTT0t/s400/z1.png
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment