Smiley face

Ife olomi tutu: Apostle Suleiman pelu aya re ninu ogba ododo

FB_IMG_1490449238409.jpg
Pelu gbogbo esun ati awuyewuye to ro mo Apostle Suleiman Johnson, olori ijo Omega Fire Ministries, o dabi eni wi pe fila mawobe ni ojise Olorun naa de sori pelu bo se n tami oge pelu aya re, Lizzy. 
 
Ti e ko ba gbagbe, Ojise Olorun yii ni omobirin oninabi kan ti oruko re n je Otobos pariwo wi pe, ololufe oun ni Apostle. 
 
Sugbon ninu oro Apostle Suleiman, o ni ibaniloruko je lasan ni eleyii ti to je ise owo awon oloselu Naijiria. 
 
Aimo isele lorileede yii ni Apostle ti dasi eleyii ti ko te awon olose Naijiria lorun, apeere iru ni oro awon Fulani  darandaran ti won pa awon onigbagbo.
FB_IMG_1490449272435.jpg
Ka ma paro ife dun, Ife olomi tutu bi omi amu le mi n fe. Ololufe mi je ki n fa e lowo dani. Ma se teti si ohun ti aye n so, iro ni won pa. Emi ti reni bi okan mi, ife olomi tutu bi omi amu. Aya mi iwo ni temi lojokojo.
FB_IMG_1490449009043.jpg


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment