Smiley face

Itan igbesi aye Ligali Mukaiba olorin apala ilu Epe 1

 Ligali Mukaiba
Iwadii to fese mule fi ye wa daju saka wi pe, awon olorin ti n sise iroyin ki orisii awon eniyan kan ti won je oniroyin to waye. 

Gege bi a se gbo, nigba iwase, awon olorin a maa royin isele to sele ni ileto tabi ilu kan ti won ti korin .fun ileto tabi ilu mii ti won ti lo da won lara ya. 

Nigba ti oju dudu, oba le waja ni ilu kan to je wi pe awon ilu odikeji le ma gbo si isele naa leyin bi osupa meta ti isele naa ti waye.

Sugbon nipase awon olorin ti enu won ki i duro, gbogbo ohun toju won ba ri maa n jewo ninu awon orin won. 

Awon eniyan a si maa gba won gbo ju awon aheso oro tiwon ba gbo laaarin awon ojo oja nla lo.
Pelu alaye mi yii, awon kan gba wi pe, awon olorin ti n sise gege bi oniroyin saaju ki awon kan to gbe ise iroyin sise wo bi ewu eleyii ti won se bi ise san-ansan.

Bi a ba n so nipa orin apala, bi Anigilaje Ayinla Omowura se n padan legbe Alake. Ogbontarigi olorin apala kan naa daleru ni ilu Epe to wa Ipinle Eko. 

Agba Olorin wo ni mo fe so nipa re lonii? 


E tesiwaju NIBI
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment