Smiley face

Iyanu sele nibi ipade adura Apostle Suleman Johnson niluu Ameriaka


Apostle Suleman Johnson ti ijo Omega Fire Ministries Worldwide wa ninu ipade nla bayii niluu Amerika. Orisiirisii ise iyanu lo si n sele nibi ipade naa, lara re ni awon aro to n dide. Bakan naa ni opolopo awon eniyan lo n gba itusile lowo ide aye.



Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment