Smiley face

Kemi Olunloyo wo gau! Enu re pada koba patapata

 
Iku ogun ni pa akinkanju. Iku omi naa si ni pa omuwe lode. Gbogbo akitiya lati gba Kemi Olunloyo sile ti pada jasi pabo bayii. Kemi Olunloyo to je oniroyin ayelujara ati omo gomina ipinle Oyo nigba kan ri, ni won ti fesun idaran ayelujara kan latari iroyin kogbakungbe to ko nipa Pasito David Ibiyeomie.

Gege bi iroyin to te wa lowo se so, omobirin naa ko si lago olopaa mo, ogba ewon lo wa bayii nibi to ti n je ewa olomi sooroso.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment