Smiley face

Obirin to gbe irun sori fun 23yrs ti di irawo apewo

Omobirin yii lo da irun ori re si fun odun metalelogun. Bakan lo so wi pe, o oun fe se afikun odun mejidinlogun (18 yrs) sii.
Sugbon sa, oju mii ni awon eniyan fi n woo nigba ti awon kan fura si wi pe oge re ki i soju lasan.
Kini ero ti yin?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment