Smiley face

Omo Ibadan ti o le sobadan. Shio!

Ibadan tia!

Se n'Ibadan tia?
Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan?
MAPO d'AYẸYẸ
Gbogbo ODÍNJÓ tia ni,
ELEKURỌ, ALEKUSỌ,
Ibo gan-an lawa o mo n'Ibadan?
BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa,

Ibi to ku taa mo ni ke e wi,
Sebi Ibadan fe pupo.

ISALE AAFA, GBAREMU,MOSFALA,
Olayemi oba mo mọ Ibadan.

AGODI to fi d'ALAKIA ISEBỌ
Mo ti gba MỌKỌLA de YEMETU ri
Emi ti gba ỌJỌỌ de SASA pada bo.
ODO ỌNA yato s'ODO ỌNA ELEWE
Meloo la fe ka n'Ibadan tiatia
Ka maa paro, Ibadan fe ju orileede ibo mii lo.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment