Smiley face

Omo ti won so lowolowo

Ti won ba n beere wi pe taani omo ti won so bayii,  Ashley Marley James, to ni oju opo @MsCuteThickChick, lori ayelujara lomo naa.

Katapila ti omoge naa gbe seyin ni opolopo awon okunrin n tele bayii lori ayelujara.

Eyin iyawo ile, e sora! Ti oko yin ba n tele @MsCuteThickChick e so fun ko pada kiakia nitori o lewu fun ilera re gidi gan an





Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment