Smiley face

Omo Unilag ku leyin to de latagbo ariya

Omo akekoo olodun kinni, Temitope Omolara, ti ogba ileewe Yunifasiti ilu Eko (University of Lagos) lo pada sinu ogba to si bere si ni bi doju iku leyin to ba okunrin kan jade lo. 

Gege bi awon ore re se so, won ni okunrin kan ti awon ko mo lo gbe e jade lo. Sugbon nigba ti Omolara de pada, o n lo inu mu mole, o n ke bi eni ara n ni, o si bere si po eje jade lenu titi ti olojo fi de.  

Awon ti oro naa se oju re so wi pe, pelu inira to banilokanje lati ri soju ni Omolara ni saaju ko to gbemi mi lojo ketalelogun osu keta odun yii.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment