Smiley face

Oruko Dino Melaye ko si ninu iwe ayeye awon akekoo ileewe ABU

Ileese iroyin Sahara Reporters tun gbe atejade iwe ayeye awon akekoo jade ile eko ABU to wa ni Zaria jade.

Sugbon oruko Dino Melaye ko si ninu iwe naa rara.

Ohun ti ileese iroyin naa fi sori ero twitter ni yii.

"@dino_melaye's name also missing from the Joint Convocation1998/99-2000/2001brochure of ABU Geography (BA) 3rd Class category"

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment