Smiley face

Senator Dino Melaye ti se afihan foto agunbaniro NYSC re nipinle Kaduna

Ogbeni Dino Melaye ti ileese iroyin Sahara Reporters fesun kan wi pe ko kawe jade nile eko ABU ti se afihan foto agunbaniro re ni akoko to wa pelu awon akegbe re ni ipinle Kaduna. 

Ninu atejade mii ti asofin to wa lati ipinle Kogi se, inu foto yii lo ti n rerin pelu akole to so wi pe, "mo n fi isubu Sowore rerin ati awon alatileyin re pata". (Ogbeni Sowore ni olootu agba fun ile ise iroyin Sahara Reporters, ile ise iroyin yii lo si gbe jade wi pe senato naa ko ni sabuke.)


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment