Smiley face

Won lo ye ki Saraki ti pada saba won. Ki lo fa sababi?

Bukola Saraki

Ogbeni ni kan ti n je Modiu Olaguro ti pe akiyesi awon omo Naijiria nipa ibi ti ilu naa de duro ati ona to n dori gba nipa awon oloselu wa ati bi awon ara ilu naa se dake bi omi inu amu si awon isele ti n sele. 

Olaguro se alaye wi pe, o ye ki awon omo Naija ti da Bukola Saraki pada si aba won pelu awon aje iwa ibaje to si moo lori nipa oko ayeta to gbe wole lai gba ojulowo iwe lowo awon asobode. O menu ba bi Obasanjo se n gbiyan lati di aare fun igba keta bakan naa lo tun so bi awon asoju se n gbe sabuke ayederu kiri. 

mmmmh nnkan mbe!

Alaye ogbeni naa ni yii nisale

It is remarkable to know that with the litany of scandals trailing Bukola Saraki, Nigerians have still not found the energy needed to send him back to his village.

We thought David Mark was at the apogee of legislative rascality until Olybukola came. Hardly a day closes without Saraki's name mentioned in reports of grand theft and high-wired larceny.

Unsurprisingly, his denial follows the same trend: the equation of his person to the senate.

This was what he did with the N298m bulletproof car he recently acquired with fake customs paper.

When this unfortunate docility of Nigerians is over, we would have to sit and ponder on how a local thief from a small enclave in Kwara rose to become a national criminal of international repute.

The National Assembly started small in 1999. With the third term ambition of the shameless megalomaniac from Ota, it quickly rose to become an assemblage of criminals and expired nonentities.

Nigerians must see the toppling of that institution of certificate forgers and buttock massagers as an emergency.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment